Àgbéṣùà
Sísọ síta
Ìtumọọ Àgbéṣùà
The god Àgbé (Ọ̀sanyìn) has created a celebration.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
àgbé-ṣe-ùà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
àgbé - Ọ̀sanyìn, the Yoruba god of magic and herbal medicineṣe - make, do, perform
ùà - the society, a gathering, celebration
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
AKURE