Èwédùnmọ́lá
Sísọ síta
Ìtumọọ Èwédùnmọ́lá
Youth is sweetened with honour or wealth.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ẹ̀we-dùn-mọ́-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ẹ̀we - youthdùn - sweet
mọ́ - add to
ọlá - prominence, prestige, wealth, honour
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI