Ọ̀tákìíyọ̀mí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọ̀tákìíyọ̀mí

The enemy will not/shall not mock me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọ̀tá-kìí-yọ̀-mí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọ̀tá - enemy
kìí - does not, never
yọ̀ - mock
- me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKO
GENERAL



Irúurú

Kìíyọ̀mí

Kìńyọ̀mí