Ọmọ́rìnádé
Pronunciation
Meaning of Ọmọ́rìnádé
The child walks into royalty.
Morphology
ọmọ-rìn-sí-adé
Gloss
ọmọ - childrìn - walk
sí - into
adé - crown, royalty
Geolocation
                        Common in:
                            
IBADAN                            
IFE                            
OTHERS                    
