Ọmọ́gbọ́lárìnwá

PronunciationMeaning of Ọmọ́gbọ́lárìnwá

The child brought wealth (to us).Extended MeaningMorphology

ọmọ-gbé-ọlá-rìn-wáGloss

ọmọ - child
gbé...wá - bring
ọlá - wealth, success, prestige
rìn - walk


Geolocation

Common in:
OTHERSFamous PersonsMedia LinksVariants

Ọmọ́gbọ́lárìn, Gbọ́lárìn, Gbọ́lárìnwá.See also