Aniyìkáyé
Sísọ síta
Ìtumọọ Aniyìkáyé
One of tremendous goodwill around the world.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
a-ní-iyì-kárí-ayé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
a - one whoní - have
iyì - value, worth, honour, goodwill
kárí - be enough for all
ayé - life, living
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
