Págà! A kò rí oun tó jọ Atan
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa? Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.

Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn


Atándèyí

Brief Meaning: Atan becomes this.


Atánbíyí

Brief Meaning: Atan has given birth to this (child).


Atándáhùnsi

Brief Meaning: Atan has answered my prayers.


Atándẹ̀rọ̀

Brief Meaning: The (water of the) goddess Atan has become a relief/solution.


Atángboyè

Brief Meaning: Atan has received honour.


Atánlóde

Brief Meaning: The goddess Atan owns the outside/the town.


Atánlógùn

Brief Meaning: Atan has supernatural/medicinal power.


Atánlóògùn

Brief Meaning: Atan has supernatural power/medicine.


Atánlúyì

Brief Meaning: Atan has honor.


Atánmúdé

Brief Meaning: Atan brought (the child) here.


Atánmútì

Brief Meaning: A shortening of Atánmútìmí, Atan placed (this child) with me.


Atánmúyìdé

Brief Meaning: Atan has brought honor.


Atánnẹ́yẹ

Brief Meaning: Atan has honor.


Atánníyì

Brief Meaning: Standardized form of the name Atánlúyì, Atan has honor.


Atánṣuyì

Brief Meaning: Atan has created honor.


Atánṣèlú

Brief Meaning: Atan created the town.


Atánṣẹ̀yẹ

Brief Meaning: Atan has created honor.