Àdùnní
Sísọ síta
Ìtumọọ Àdùnní
The one pleasant to have. Sweet personality.
Àwọn àlàyé mìíràn
A cognomen, oríkì.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
à-dùn-ní
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
à - one whodùn - sweet
ní - have
Agbègbè
                        Ó pọ̀ ní:
                            
GENERAL                    
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Àdùnní Olórìṣà (Susanne Wenger). Austrian-Nigerian artist (1915-2009)
