Gbèjà

Sísọ síta



Ìtumọọ Gbèjà

Support (in a fight). See: Adégbèjà, Olúgbèjà, etc



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

gbè-ìjà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

gbè - support, benefit, befit
ìjà - fight, struggle


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Adégbìjà

Adégbèjà

Gbìjà

Olúgbìjà

Olúgbèjà

Ògúngbèjà

Ògúngbìjà

Oyègbìjà

Ọ̀ṣúngbìjà

Ọ̀súngbèjà

Ilégbìjà