Págà! A kò rí oun tó jọ Gbọ́lá
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.
Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Gbólábọ̀
Brief Meaning: He/she brings success/nobility back.
Gbọláṣiré
Brief Meaning: Plays with wealth.
Gbọ́lága
Brief Meaning: Elevate (our) honour.
Gbọ́lágadé
Brief Meaning: Bring honour along onto royalty.
Gbọ́lágùntẹ́
Brief Meaning: Put nobility on the throne.
Gbọ́láwọlé
Brief Meaning: Bring honour into the home.
Gbọ́láwọyì
Brief Meaning: Make nobility/success more glorious.
Gbọ́láyẹmí
Brief Meaning: Give me the courtesy I deserve. Make nobility fitting for me.
Gbọ́láṣeré
Brief Meaning: (One who) has wealth to play around with.
Gbọ́ládé
Brief Meaning: (One who) brought wealth.
Gbọ́láhàn
Brief Meaning: (One who) reflects wealth.
Gbọ́láró
Brief Meaning: (That which) upholds honor, a shortening of names like Ọmọ́gbọ́láró, Ògúngbọ́láró.
Gbọ́lágún
Brief Meaning: Make nobility/success/wealth complete.