Mojèrèọlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Mojèrèọlá

I have earned the benefit of honour.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mo-jẹ-èrè-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

mo - I
jẹ - achieve, enjoy
èrè - reward
ọlá - honour, wealth, nobility, success


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Mojèrè

Jèrèọlá