Motọ́lání
Sísọ síta
Ìtumọọ Motọ́lání
1. I'm great enough to have nobility/success/honour. 2. I have honour/success/nobility anew.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
mo-tó-ọlá-ní, mo-tún-ọlá-ní
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
mo - Itó - sufficient enough for
ọlá - wealth
ní - have
tún - again, afresh, anew
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL