Págà! A kò rí oun tó jọ "Múkòmí"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Ifámúkòmí
Meaning: Ifá gave me this (child).
Ògúnmúkòmí
Meaning: Ògún brought him/her to me.
Ọlọ́fínmúkò
Meaning: A shortening of Ọlọ́fínmúkòmí, Ọlọ́fin gave this child (to me).
Ọ̀shámúkò
Meaning: A shortening of Ọ̀shámúkòmí or Ọ̀ṣámúkòmí, Ọ̀rìṣà gave it (this child) to me.
Ọ̀gbẹ̀sẹ́múkò
Meaning: A shortening of Ọ̀gbẹ̀sẹ́múkòmí, Ọ̀gbẹ̀sẹ̀ gave (this child) to me.
Ọ̀sanyínmúkò
Meaning: Ọ̀sanyìn gave this (child) to me.