Págà! A kò rí oun tó jọ "Nẹ́yẹ"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Ajínẹ́yẹ
Meaning: Same as Ajílẹ́yẹ.
Atánnẹ́yẹ
Meaning: Atan has honor.
Ẹgbẹ́nẹ́yẹ
Meaning: Teamwork has honour.
Ọdẹ́nẹ́yẹ
Meaning: The hunter has value.
Odùnẹ́yẹ
Meaning: Odù (Ifá) has honor.
Okùnẹ́yẹ
Meaning: The (Ìjẹ̀bú) god of wealth has honour.
Ọrẹ̀nẹ́yẹ
Meaning: The deity Ọrẹ̀ has honor.
Oshónẹ́yẹ
Meaning: A variant of Oṣónẹ́yẹ, The sorcerer has honor/prestige.
Ọ̀sínẹ́yẹ
Meaning: The king has honour.
Oyènẹ́yẹ
Meaning: The chieftaincy title has honour.
Oyèròkun
Meaning: Honor has journeyed to the ocean.