Ògúntìmílẹ́hìn

PronunciationMeaning of Ògúntìmílẹ́hìn

Ogun supports/backs me.Extended MeaningMorphology

ògún-tì-mí-l-ní-ẹ́hìnGloss

ọ̀gún - Ògún, the god of iron
tì - push
mí - me
ní - at
ẹ̀yìn - back


Geolocation

Common in:Famous PersonsMedia LinksVariants

Ògúntìmílẹ́yìn, Ògúntìmẹ́yìn, Ògúntìmẹ́hìn,See also