Págà! A kò rí oun tó jọ "Pìtàn"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adépìtàn
Meaning: The crown tells a story.
Akínpìtànsóyè
Meaning: The warrior has added a story/history to honor/chieftaincy.
Amúpìtàn
Meaning: Someone (that will be) used to tell stories (or testimonies).
Àńpìtàn
Meaning: We are telling a story.
Àrípìtàn
Meaning: A child whose presence is valuable for telling stories.
Awópìtàn
Meaning: Ifá/Ifá priest told the story/revealed something unknown (with the birth of the child).
Fèyípìtàn
Meaning: One with whom to tell stories.
Odùpìtàn
Meaning: The Odù tells stories.
Ọrẹ̀pìtàn
Meaning: Ọrẹ̀ (used this child) to add a story/history.
Ọṣhínpìtàn
Meaning: The Ọshìn tells a story.
Ọṣínpìtàn
Meaning: The King tells a story.