Págà! A kò rí oun tó jọ Yọkùn
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.
Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adéyọkùn
Brief Meaning: The crown has grown a potbelly (has grown wealthy).
Akínmáyọ̀kún
Brief Meaning: The warrior made joy full.
Akínyọkùn
Brief Meaning: The warrior has grown a potbelly (grown wealthy).
Awóyọkùn
Brief Meaning: The oracle has grown a potbelly (has grown wealthy).
Ayòkún
Brief Meaning: Abundant joy.
Ayọ̀kúnbi
Brief Meaning: Joy has been added to our family.
Ayọ̀kúnsí
Brief Meaning: Joy has further added up.
Ayọ̀kúnmi
Brief Meaning: I'm filled with joy.
Ayọ̀kúnnú
Brief Meaning: Joy fills (my) inside.
Ayọ̀kúnnúmi
Brief Meaning: I am full of joy.
Ayọ̀kúnlé
Brief Meaning: Joy fills the house.
Fáyọkùn
Brief Meaning: Ifá grew a fat belly.
Láyọkùn
Brief Meaning: Wealth/Nobility expanded/flourished.
Máyọ̀kún
Brief Meaning: Make joy full.
Olúwámáyọ̀kún
Brief Meaning: The Lord made (my) joy full.
Owóyọkùn
Brief Meaning: Money grew a potbelly.
Ìjíyọkùnọlà
Brief Meaning: The act of waking up has brought forth wealth/riches.
Ọláyọkùn
Brief Meaning: Wealth grew.
Ọlọ́fínyọkùn
Brief Meaning: Olofin has grown a potbelly (has grown wealthy).
Ògúnyọkù
Brief Meaning: A variation of Ògúnyọkùn, Ògún has grown a potbelly (has grown wealthy).