Ọlúájẹ́milà
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọlúájẹ́milà
The god Ọlúa allowed me to live.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlúa-jẹ́-mi-là
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlúa - An Èkìtì/Àkúrẹ́ sky and fertility god, also known as Ọlúayé or Àtogùnmòjòjẹ́ - permit, to exist, to be effective
mi - me, mine
là - open, survive
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI