Págà! A kò rí oun tó jọ "Bíyìí."
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Akínbíyì
Meaning: Valor gave birth to this.
Owóbíyì
Meaning: Wealth begat this.
Èṣùbíyí
Meaning: Èṣù birthed this (child).
Eégúnbiyì
Meaning: The masquerade gave birth to value.
Ifábíyí
Meaning: Ifá birthed this (child).
Ọ̀ṣúnbíyí
Meaning: Ọ̀ṣun gave birth to this.
Ọ̀gábíyí
Meaning: The leader has gave birth to this (child).
Atánbíyí
Meaning: Atan has given birth to this (child).