Págà! A kò rí oun tó jọ "Dọjà"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adédọjà
Meaning: The crown becomes valuable.
Ìbídọjà
Meaning: Birth became a market.
Ládọjà
Meaning: See: Ọládọjà: "Honour has become (famous/widely beloved/boisterous) like the marketplace".
Ògúndọjà
Meaning: See: Adédọjà, Ọládọjà, Ọ̀ṣúndọjà, etc
Ọládọjà
Meaning: Honour has become the market. Honour has become (famous/widely beloved/boisterous) like the marketplace.
Ọ̀pádọja
Meaning: The (child of) Ọpá deity has become renowned (like the marketplace).
Ọ̀ṣúndọjà
Meaning: The goddess Ọ̀ṣun has become prosperous (like a marketplace).