Págà! A kò rí oun tó jọ "Dípọ̀"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Afìdípọ̀tẹ̀mọ́lẹ̀
Meaning: One who is capable of using reasoning to stop rebellion.
Fìdípọ̀tẹ̀
Meaning: One capable of killing off a rebellion (from the source). See: Afìdípọ̀tẹ̀mọ́lẹ̀.
Ládípọ̀
Meaning: Wealth/Nobility/Success becomes plenty.
Ṣódípọ̀
Meaning: A variant of Ṣódiípọ̀, The sorcerer has become a multitude.
Ọládipọ̀
Meaning: Wealth becomes many.
Ṣodiípọ̀
Meaning: The sorcerer has become a multitude.