Págà! A kò rí oun tó jọ "Jọkẹ́"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adéjọkẹ́
Meaning: 1. The crown takes care of this, together. 2. One who has come to be pampered.
Àjọkẹ́
Meaning: Jointly cherished, jointly beloved.
Aládéjọkẹ́
Meaning: The crowned heads jointly care for this.
Bólújọkẹ́
Meaning: Care for this child, in collaboration with the prominent ones.
Gbanejọkẹ́
Meaning: Two hundred people gathered to care for him/her. A multitude cares for him/her.
Ìbíjọkẹ́
Meaning: (One that) family pampers together.
Ifájọkẹ́
Meaning: One Ifá joins in to care for.
Oyèjọkẹ́
Meaning: Honour gathered to cherish (this one).