Págà! A kò rí oun tó jọ "Relé"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adénrelé
Meaning: The crown is heading home.
Adérelé
Meaning: The crown has returned home.
Akéréle
Meaning: One that has been tough from a young age.
Akínmúrelé
Meaning: What valor took home.
Akínrelé
Meaning: Valor departs for home.
Akínrelérẹ̀
Meaning: The valiant one has gone to his home.
Awórelé
Meaning: Ifá priest/initiate has gone home.
Déńrelé
Meaning: The crown is heading home.
Akínrulí
Meaning: A variant of Akínrelé, the warrior is heading home.
Olú
Meaning: 1. The head. 2. The prominent one. 3. The lord. 4. God (olúwa) 5. The hero/champion
Akérékorò
Meaning: One sour enough as a young chap.
Akéréburú
Meaning: One tough enough as a young child.