Págà! A kò rí oun tó jọ "Wùsì"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adéwùsì
Meaning: Royalty multiplies/is influential.
Akínwùsì
Meaning:
Àyánwùsì
Meaning: The drummer is famous/notable.
Ìlúwùsì
Meaning: The town is prominent.
Olúwùsì
Meaning: Prominence has increased.
Oròwùsì
Meaning: The Orò cult has achieved notability.
Oyèwùsì
Meaning: The title gains reputation.
Òbíwùsì
Meaning: Parents have grown in prominence/reputation (because of the child).
Ògúnwùsì
Meaning: Ogún has grown in reputation/prominence.
Ọbáwùsì
Meaning: The king's fame spreads.
Ọdẹ́wùsì
Meaning: The hunter has become famous.
Ọláwùsì
Meaning: Nobility is notable.
Ẹniìtàn
Meaning: 1. A historical personage, one born in ways and manners to be remembered. 2. a person with history. (Translation courtesy of Prof. Kole Ọmọ́tọ́ṣọ́)
Ògúnnọ́rìn
Meaning: Ògún is famous.
Ògúnnòìkí
Meaning: Ògún has notability.
Ògúnjẹ́milúsì
Meaning: 1. Ògún allowed me to be successful, notable. 2. Ògún, let me be successful, notable.
Olúgbùsì
Meaning: Prominence increased.
Ọláfùsì
Meaning: Honor has become well-established (in a family).
Fùsì
Meaning: To become well known, a shortened form of many names like Adéfùsì, Ògúnfùsì, Akínfùsì, etc.
Akínfùsì
Meaning: The warrior has grown in notability.
Ògúnfùsì
Meaning: Ògún has grown in notability.
Ìlúgbùsì
Meaning: The town is notable.