Fájuyì

Sísọ síta



Ìtumọọ Fájuyì

Ifá did not permit honour to waste.



Àwọn àlàyé mìíràn



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

(i)fá-(à)-jẹ-(kí)-uyì-(gbé)



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination/priesthood/corpus
- does not
jẹ́ - let
uyì - honour, value
gbé - waste


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

Lt. Colonel Adékúnlé Fájuyì (26 June 1926 – 29 July 1966): former military administrator of Western Nigeria, assassinated alongside his Commander, Major General Aguiyi Ironsi in a counter coup in Ibadan.



Ibi tí a ti lè kà síi



Irúurú

Ifájuyigbé, Fájuyìgbé



Ẹ tún wo