Ọmọ́juwà

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọmọ́juwà

The child is our legacy. The child won't let our legacy go to waste.



Àwọn àlàyé mìíràn



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọmọ-ju-ìwà-gbé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọmọ - child
jù...gbé - will not let go to waste
ìwà - character, legacy
-


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OKITIPUPA



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

Japhet Ọmọ́juwà, Nigerian blogger.



Ibi tí a ti lè kà síi

http://www.omojuwa.com



Irúurú

Ọmọ́juwàgbé



Ẹ tún wo