Ẹ̀kúnọlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Ẹ̀kúnọlá

The fulfilment of honor.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ẹ̀-kún-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ẹ̀ - the act of
kún - in addition to, fulfillment
ọlá - honour, wealth, success, notability


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI