Ṣàngóbáyọ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Ṣàngóbáyọ̀
1. The òrìṣà Sàngó meets joy. 2. Ṣàngó gave birth to joy.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ṣàngó-bá-ayọ̀, ṣàngó-bí-ayọ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
Ṣàngó - the Yorùbá god of thunderbá - meet
bí - give birth to
ayọ̀ - joy
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OYO