Ṣíjúwadé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ṣíjúwadé
(One who) glimpses royalty.
Àwọn àlàyé mìíràn
The name is also sometimes written as "Ṣíjúadé"
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ṣí-ojú-wo-adé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ṣí - openojú - eyes
wo - look at, observe
adé - crown
Agbègbè
                        Ó pọ̀ ní:
                            
IFE                    
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
- Ọba Okùnadé Ṣíjúwadé Olúbùṣe 
- the 50th Ọọ̀ni of Ifẹ (1980 - 2015). 
