Ṣọ́lédolú

Sísọ síta



Ìtumọọ Ṣọ́lédolú

One who watches the house in wait for the prominent one.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ṣọ́-ilé-de-olú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ṣọ́ - watch (over)
ilé - house, home
dè - while waiting for
olú - lord, the prominent one, the leader


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Dolú

Shọ́lédolú