Ṣàngówándé

Sísọ síta



Ìtumọọ Ṣàngówándé

Sango seeks and finds me,



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ṣàngó-wá-n-dé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ṣàngó - the Yorùbá god of thunder
wá...dé - seek
n - me (mi)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Wándé