Ṣódádé

Sísọ síta



Ìtumọọ Ṣódádé

The sorcerer has a crown on.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oṣó-dé-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oṣó - sorcerer, òrìṣà oko
dé - sport
adé - crown


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OGUN