Ṣódípẹ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Ṣódípẹ̀

The sorcerer has granted my request.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oṣó-dípẹ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oṣó - sorcerer
dípẹ̀ - grant one's request


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU