Ṣófolúwẹ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Ṣófolúwẹ̀

The sorcerer bathes with notability/success.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọṣó-fi-olú-wẹ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oṣó - sorcerer
fi - use
olú - prominence, notability
wẹ̀ - bathe, delight


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OGUN



Irúurú

Shófolúwẹ̀