Ṣófowótẹ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Ṣófowótẹ̀

One the sorcerer used money to commission. [verification needed]



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọṣó-fi-owó-tẹ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oṣó - sorcerer
fi - use
owó - money
tẹ̀ - press


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OGUN



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

  • Ṣẹ́gun Ṣófowótẹ̀

  • Nigerian music composer.