Ṣógbóyèga
Sísọ síta
Ìtumọọ Ṣógbóyèga
The sorcerer elevated honour.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oṣó-gbé-oyè-ga
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oṣó - sorcerergbé...ga - lift up, elevate
oyè - honour, chieftaincy
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Jacob Sógbóyèga Odulate aka Blessed Jacob (1884-1962)
a Nigerian pharmacist
inventor and entrepreneur in 1918.