Ṣómọ̀rìn
Sísọ síta
Ìtumọọ Ṣómọ̀rìn
The sorcerer walks well.
Àwọn àlàyé mìíràn
The larger implication of this name is that the child, born to the family of sorcerers, came at the right time, hence "walks well."
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oṣó-mọ̀ọ́-rìn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oṣó - sorcerermọ̀ọ́ - knows how to
rìn - walk