Ṣónẹ́kàn
Sísọ síta
Ìtumọọ Ṣónẹ́kàn
The fertility god has got an offshoot.
Àwọn àlàyé mìíràn
Oṣó is also often interpreted as 'sorcerer'.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
(o)ṣó-ní-ẹkàn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oṣó - sorcerer, the fertility godní - have
ẹkàn - ofshoot
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OGUN
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Chief Ernest Shónẹ́kàn
9th President of Nigeria 26 August 1993 – 17 November 1993 Lawyer
Industrialist and Politician.