Ṣóríyàn
Sísọ síta
Ìtumọọ Ṣóríyàn
The child whom the sorcerer (or the Òrìsà oko) has deliberately selected.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oṣó-rí-yàn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oṣó - sorcerer, the fertility deity (òrìṣà oko)rí - see, find
yàn - choose, select
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA
IJEBU