Ṣósimi
Sísọ síta
Ìtumọọ Ṣósimi
The sorcerer rests.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oṣó-sinmi
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oṣó - sorcerer, fertility god (Òrìṣà oko)sinmi - rest
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OGUN
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Délé Ṣósimi: Afrobeat musician