Ṣótọ́lá
Sísọ síta
Ìtumọọ Ṣótọ́lá
The Ọṣọ́ suffices for wealth.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
(o)ṣó-tó-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oṣó - sorcerer, Oṣó divinity of fertility and farming, òriṣa okotó - suffice for, enough for
ọlá - wealth
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU