Ṣówẹ̀mímọ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Ṣówẹ̀mímọ́

The sorcerer washed me clean.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oṣó-wẹ̀-mí-mọ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oṣó - sorcerer, the god of farming
wẹ̀ - bathe, wash
- me
mọ́ - holy, clean


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU



Irúurú

Wẹ̀mímọ́

Shówẹ̀mímọ́