Ṣófẹlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Ṣófẹlá

The sorcerer has expanded/increased honor.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oṣó-fẹ̀-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oṣó - sorcerer, òrìṣà oko, the god of fertility
fẹ̀ - spread, enjoy
ọlá - wealth, prestige, honour, nobility, benefit


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OGUN



Irúurú

Fẹlá

Shófẹlá

Oṣófẹlá