Ṣówándé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ṣówándé
The sorcerer has sought me here.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oṣó-wá-n-dé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oṣó - sorcerer, òrìṣà oko, the god of fertilitywá - come, arrive
n - me (mi)
dé - arrive, return
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OGUN
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Fẹlá Ṣówándé
Nigerian musician.