Ẹbíṣùrùkẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Ẹbíṣùrùkẹ́

One that the whole clan has come together to care for.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ẹbí-ṣùrù-kẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ẹbí - family, clan
ṣùrù - surround
kẹ́ - cherish, care for


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ẹbíṣùkẹ́