Ọ̀ṣìnúgà
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọ̀ṣìnúgà
The child has a throne.
Àwọn àlàyé mìíràn
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọṣìn-ní-ugà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oṣìn - the childní - have, own
uga - throne
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OGUN