Ọ̀ṣúnmúyìíwá
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọ̀ṣúnmúyìíwá
Ọ̀ṣun brought this.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọ̀ṣun-mú...wá-èyí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọ̀ṣun - Yorùbá river goddess of fertility and beautymú...wá - bring
èyí - this (one)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
OSUN