Ọbasakin
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọbasakin
1. Ọbàtálá is brave. 2. The king is brave. 3. Ọbalúayé is brave.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọba-ṣe-akin
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọba - king, spirit of ọbalúayé, Ọbàtáláṣe - make, create (something good), do
akin - valor, bravery, the warrior
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL