Ọlániáwò

Sísọ sítaÌtumọọ Ọlániáwò

Success is what we should look at.Àwọn àlàyé mìírànÌtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-ni-kí-á-wòÌtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - wealth, success, nobility
ni - is
kí - what
- we
wò - watch, look at, pay attention to


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERALÀwọn Ènìyàn Gbajúọ̀Ibi tí a ti lè kà síiIrúurú

TadéniáwòẸ tún wo