Ọlọ́runtósìn

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlọ́runtósìn

Same as Olúwatósìn: God is worth serving/worshipping.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlọ́run-tó-sìn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlọ́run - God
- suffice for
sìn - worship, serve


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OGUN



Irúurú

Tósìn